Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 19:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì lọ sí Náíótì ni Rámà. Ṣùgbọ́n, ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé e lórí ó sì ń lọ lọ́nà, ó sì ń ṣọtẹ́lẹ̀ títí tí ó fi dé Náíótì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 19

Wo 1 Sámúẹ́lì 19:23 ni o tọ