Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 19:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sọ fún Jónátanì ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé kí wọ́n pa Dáfídì. Ṣùgbọ́n Jónátanì fẹ́ràn Dáfídì púpọ̀

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 19

Wo 1 Sámúẹ́lì 19:1 ni o tọ