Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gòláyátì dìde, ó sì kígbe sí ogun Ísírẹ́lì pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi jáde wá, tí ẹ ṣe tò fún ogun? Ṣé èmi kì í ṣe Fílístínì ni, àbí ẹ̀yin kì í ṣe ìránṣẹ́ Ṣọ́ọ̀lù? Yan ọkùnrin kan kí o sì jẹ́ kí ó sọ̀kalẹ̀ wá sí ọ̀dọ̀ mi.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:8 ni o tọ