Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 17:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn tí ó péjọ níbí ni yóò mọ̀ pé kì í ṣe nípa ọ̀kọ̀ tàbí idà ni Olúwa fi ń gbàlà; ogun náà ti Olúwa ni, yóò sì fi gbogbo yín lé ọwọ́ ọ wa.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:47 ni o tọ