Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 17:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ṣe ń bá wọn sọ̀rọ̀, Gòláyátì akíkanjú Fílístínì tí ó wá láti Gátì yọra sí iwájú ní ojú ogun, ó sì kígbe fún ìpèníjà, Dáfídì sì gbọ́.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:23 ni o tọ