Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí, ẹ̀mi Olúwa ti kúrò lára Ṣọ́ọ̀lù, ẹ̀mi búburú láti ọ̀dọ̀ Olúwa sì ń yọ ọ́ lẹ́nu.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 16

Wo 1 Sámúẹ́lì 16:14 ni o tọ