Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 15:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Sámúẹ́lì wí pé,“Bí idà rẹ ti sọ àwọn obìnrin di aláìní ọmọbẹ́ẹ̀ ni ìyá rẹ yóò sì di aláìní ọmọ láàárin obìnrin.”Sámúẹ́lì sì pa Ágágì níwájú Olúwa ni Gílígálì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 15

Wo 1 Sámúẹ́lì 15:33 ni o tọ