Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọ̀nà tí Jónátanì ti ń fẹ́ láti kọjá dé ìlú olódi àwọn Fílístínì, ní bèbè òkúta mímú kan wá, orúkọ èkíní sì ń jẹ́ Bóṣéṣì, orúkọ èkejì sì ń jẹ́ Sénè.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:4 ni o tọ