Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 14:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ogun sọ fún un pé, “Baba rẹ fi ègún kìlọ̀ fún àwọn ọmọ ogun wí pé, ‘Ègbé ni fún ẹni tí ó jẹ oúnjẹ ní òní!’ Ìdí nìyìí tí àárẹ̀ fi mú àwọn ènìyàn.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:28 ni o tọ