Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Sámúẹ́lì kúrò ní Gílígálì, ó sì gòkè lọ sí Gíbéà ti Bẹ́ńjámínì, Ṣọ́ọ̀lù sì ka àwọn ènìyàn tí ó wà lọ́dọ̀ ọ rẹ̀, wọ́n sì jẹ́ ẹgbẹ̀ta.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13

Wo 1 Sámúẹ́lì 13:15 ni o tọ