Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 13:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ṣọ́ọ̀lù sì jẹ́ ọmọ ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jọba, ó sì jọba lórí Ísírẹ́lì ní ọdún méjìlélógójì.

2. Ṣọ́ọ̀lù yan ẹgbẹ̀ẹ́dógún (3000) ọkùnrin ní Ísírẹ́lì, ẹgbẹ̀rún méjì (2000) sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀ ní Míkimásì àti ní ìlú òkè Bẹ́tẹ́lì ẹgbẹ̀rún kan (1000) sì wà lọ́dọ̀ Jónátanì ní Gíbéà ti Bẹ́ńjámínì. Àwọn ọkùnrin tókù ni ó rán padà sí ilé e wọn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13