Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lẹ́yìn ìgbà tí Jákọ́bù wọ Éjíbítì, wọ́n ké pe Olúwa fún ìrànlọ́wọ́, Olúwa sì rán Mósè àti Árónì, tí wọ́n mú àwọn baba ńlá yín jáde láti Éjíbítì láti mú wọn jókòó níbí yìí.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:8 ni o tọ