Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 12:23-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Bí ó ṣe ti èmi ni, kí á má rí i pé èmi dẹ̀ṣẹ̀ sí Olúwa nípa dídẹ́kun àti gbàdúrà fún un yín. Èmi yóò sì kọ́ ọ yín ní ọ̀nà rere àti ọ̀nà òtítọ́.

24. Ṣùgbọ́n ẹ rí i dájú pé, ẹ bẹ̀rù Olúwa, kí ẹ sì sìn ín nínú òtítọ́ pẹ̀lú gbogbo ọkàn an yín; Ẹ kíyèsí ohun ńlá tí ó ti ṣe fún un yín.

25. Ṣíbẹ̀ bí ẹ̀yin bá ń ṣe búburú, ẹ̀yin àti ọba yín ni a ó gbá kúrò.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12