Nígbà náà ni Sámúẹ́lì ké pe Olúwa, Olúwa sì rán ààrá àti òjò ní ọjọ́ náà. Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ènìyàn sì bẹ̀rù Olúwa àti Sámúẹ́lì púpọ̀.