Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 12:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin bá bẹ̀rù Olúwa àti bí ẹ̀yin bá ń sìn ín, tí ẹ sì gbọ́ tirẹ̀, tí ẹ̀yin kò sì ṣọ̀tẹ̀ sí àṣẹ rẹ̀, àti tí ẹ̀yin àti ọba tí ó jẹ lórí yín bá ń tẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run yín: ó dára

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:14 ni o tọ