Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kégbe pe Olúwa, wọ́n sì wí pé, ‘Àwa ti ṣẹ̀; a ti kọ Olúwa sílẹ̀, a sì ti sin Báálì, àti Ásítarótì. Ṣùgbọ́n nísinsìn yìí gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, àwa yóò sì sìn ọ́.’

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:10 ni o tọ