Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ ṣáájú mi sí Gílgálì. Èmi yóò sọ̀kalẹ̀ tọ̀ ọ́ wá láti rú ẹbọ sísun àti láti rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀, ṣùgbọ́n ìwọ gbọdọ̀ dúró fún ọjọ́ méje títí èmi yóò fi wá sí ọ̀dọ̀ rẹ láti sọ fún ọ ohun tí ó yẹ tí ìwọ yóò ṣe.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 10

Wo 1 Sámúẹ́lì 10:8 ni o tọ