Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ bá kúrò lọ́dọ̀ mi lónìí, ìwọ yóò bá ọkùnrin méjì pàdé lẹ́bàá ibojì Rákélì ní Sélísà, ní agbégbé Bẹ́ńjámínì. Wọ́n yóò sọ fún ọ pé, ‘Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ìwọ jáde lọ láti wá ní wọn tí rí. Nísinsìn yìí, baba à rẹ tí dákẹ́ kò ronú nípa wọn mọ́, ó sì ń damú nípa à rẹ. Ó ń béèrè, “Kí ni èmi yóò ṣe nípà ọmọ mi?” ’

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 10

Wo 1 Sámúẹ́lì 10:2 ni o tọ