Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí, arákùnrin baba Ṣọ́ọ̀lù béèrè lọ́wọ́ Ṣọ́ọ̀lù àti ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Níbo ni ẹ lọ?”Ó wí pé, “À ń wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,” ṣùgbọ́n nígbà tí a kò rí wọn, a lọ sí ọ̀dọ̀ Sámúẹ́lì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 10

Wo 1 Sámúẹ́lì 10:14 ni o tọ