Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Eléyìí sì máa ń ṣẹlẹ̀ ní ọdọọdún. Nígbàkígbà tí Hánà bá gòkè lọ sí ilé Olúwa, orogún rẹ̀ a máa fín-in níràn títí tí yóò fi máa sunkún tí kò sì ní lè jẹun.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 1

Wo 1 Sámúẹ́lì 1:7 ni o tọ