Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hánà sì wí pé, “Olúwa mi, bí ọkàn rẹ ti wà láàyè, Olúwa mi, èmi ni obìnrin náà tí ó dúró lẹ́bàá ọ̀dọ̀ rẹ níhìn-ín tí ń tọrọ lọ́dọ̀ Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 1

Wo 1 Sámúẹ́lì 1:26 ni o tọ