Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ìwọ bá rìn níwájú mi ní ọkàn òtítọ́ àti ìdúró ṣinṣin, bí i Dáfídì baba rẹ ti rìn, kí o sì ṣe gbogbo èyí tí mo ti paláṣẹ fún ọ àti kí o sì pa àṣẹ mi àti òfin mi mọ́,

Ka pipe ipin 1 Ọba 9

Wo 1 Ọba 9:4 ni o tọ