Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 9:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n, Sólómónì kò fi ẹnìkankan ṣe ẹrú nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì; àwọn ni ológun rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àti àwọn ìjòyè rẹ̀, àti àwọn balógun rẹ̀, àti àwọn olórí kẹ̀kẹ́ rẹ̀ àti ti àwọn ẹlẹ́sin rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 9

Wo 1 Ọba 9:22 ni o tọ