Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ohun kankan nínú àpótí-ẹ̀rí bí kò ṣe tábìlì òkúta méjì tí Mósè ti fi sí ibẹ̀ ní Hórébù, níbi tí Olúwa ti bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú, lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:9 ni o tọ