Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:63 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì rú ẹbọ ọrẹ àlàáfíà sí Olúwa: ẹgbàá mọ́kànlá (22,000) màlúù, àti ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) àgùntàn. Bẹ́ẹ̀ ni ọba àti gbogbo àwọn omọ Ísírẹ́lì ya ilé Olúwa sí mímọ́.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:63 ni o tọ