Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Jẹ́ kí ojú rẹ sí sí ẹ̀bẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ, àti sí ẹ̀bẹ̀ àwọn ènìyàn rẹ Ísírẹ́lì, kí o sì tẹ́tí sílẹ̀ sí wọn nígbà tí wọ́n bá kégbe sí ọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:52 ni o tọ