Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bí wọ́n bá sì fi gbogbo àyà àti gbogbo ọkàn wọn yípadà sí ọ, ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn, tí ó kó wọn ní ìgbèkùn lọ, tí wọ́n sì gbàdúrà sí ọ sí ìhà ilẹ̀ wọn tí ìwọ ti fi fún àwọn baba wọn, Ìlú tí ìwọ ti yàn, àti ilé tí èmi kọ́ fún orúkọ rẹ;

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:48 ni o tọ