Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà tí àdúrà tàbí ẹ̀bẹ̀ bá ti ọ̀dọ̀ ẹnìkan láti ọ̀dọ̀ gbogbo Ísírẹ́lì wá, tí olúkúlùkù sì mọ ìbànújẹ́ ọkàn rẹ̀, bí ó bá sì tẹ́ ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì sí ìhà ilé yìí,

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:38 ni o tọ