Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà náà ni kí o gbọ́ láti ọ̀run wá, kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ jìn wọ́n, à ní Ísírẹ́lì, ènìyàn rẹ. Kọ́ wọn ní ọ̀nà tí ó tọ́ láti máa rìn, kí o sì rọ òjò sí ilẹ̀ tí ìwọ ti fi fún ènìyàn rẹ fún ìní.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:36 ni o tọ