Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n nítòótọ́ Ọlọ́run yóò máa gbé ayé bí? Ọ̀run àti ọ̀run àwọn ọ̀run kò le gbà ọ́. Kí a má sọ pé ilé yìí tí mo kọ́ fún ọ!

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:27 ni o tọ