Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì sì dúró níwájú pẹpẹ Olúwa, níwájú gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì, ó sì na ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì sókè ọ̀run.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:22 ni o tọ