Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Sólómónì pe àwọn àgbà Ísírẹ́lì àti gbogbo àwọn olórí àwọn ẹ̀yà àti àwọn olórí ìdílé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jọ papọ̀ níwájú rẹ̀ ní Jérúsálẹ́mù, láti gbé àpótí-ẹ̀rí májẹ̀mú Olúwa wá láti ìlú Dáfídì, tí ń ṣe Ṣíónì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:1 ni o tọ