Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọ̀nyí láti òde dé apá àgbàlá ńlá, àti láti ìpìlẹ̀ dé ìbòrí òkè ilé, wọ́n sì jẹ́ òkúta iyebíye gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n òkúta gbígbẹ, tí a fi ayùn rẹ́ nínú àti lóde.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:9 ni o tọ