Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fi ọ̀wọ̀n ṣe gbàngàn ìdájọ́: àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn rẹ̀, ìbú rẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n (30) ìgbọ̀nwọ́. Ìloro kan sì wà níwájú rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀wọ̀n àti ìbòrí ìgúnwà níwájú wọn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:6 ni o tọ