Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí gbogbo iṣẹ́ tí Sólómónì ọba ṣe fún ilé Olúwa parí, ó mú gbogbo nǹkan tí Dáfídì baba rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wá; fàdákà, wúrà àti ohun èlò, ó sì fi wọ́n sínú ìṣúra ilé Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:51 ni o tọ