Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lókè ẹṣẹ̀ náà ni àyíká kan wà tí ó jẹ́ ààbọ̀ ìgbọ̀nwọ́ ní jíjìn. Ẹ̀gbẹ́ etí rẹ̀ àti àlàfo ọ̀nà àárin rẹ̀ ni a ṣo mọ́ òkè ẹsẹ̀ náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:35 ni o tọ