Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kẹ̀kẹ́ mẹ́rin sì wà nísàlẹ̀ àlàfo ọ̀nà àárin a sì so ọ̀pá àyíká kẹ̀kẹ́ náà mọ́ ẹsẹ̀ náà. Gíga àyíká kẹ̀kẹ́ kan sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan àti ààbọ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:32 ni o tọ