Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lórí àlàfo ọnà àárin tí ó wà lágbedeméjì ni àwòrán kìnnìún, màlúù, àti àwọn kérúbù wà, àti lórí ìpàdé etí bákan náà. Lókè àti nísàlẹ̀ àwọn kìnnìún, màlúù sì ni iṣẹ́ ọ̀ṣọ́ wà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:29 ni o tọ