Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dúró lórí màlúù méjìlá, mẹ́ta kọjú sí àríwá, mẹ́ta sì kọjú sí ìwọ̀ oòrùn, mẹ́ta kọjú sí gúṣù, mẹ́ta sì kọjú sí ìlà oòrùn. Agbada náà sì jókòó lórí wọn, gbogbo apá ẹ̀yìn wọn sì ń bẹ nínú.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:25 ni o tọ