Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé àwọn ọ̀wọn náà ró ní ìloro tẹ́ḿpìlì, ó sì pe orúkọ ọ̀wọ̀n tí ó wà ní gúṣù ní Járánì àti èyí tí ó wà ní àríwá ní Bóásì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:21 ni o tọ