Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kọ́ ilé igbó Lébánónì pẹ̀lú; gígùn rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn ún ìgbọ̀nwọ́, àti àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́ ní ìbú rẹ̀ àti gíga rẹ̀ ọgbọ̀n ìgbọ̀nwọ́; pẹ̀lú ọwọ́ mẹ́rin igi kédárì, àti ìdábú igi kédárì lórí òpó náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:2 ni o tọ