Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 4:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì fún Sólómónì ní ọgbọ́n, àti òye ní ọ̀pọ̀lọpọ̀, àti ìmọ̀ gbígbòrò òye tí a kò le è fi wé iyanrìn tí ó wà létí òkun.

Ka pipe ipin 1 Ọba 4

Wo 1 Ọba 4:29 ni o tọ