Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 4:15-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Áhímásì ní Náfítalì; ó fẹ́ Básémátì ọmọbìnrin Sólómónì ní aya;

16. Báánà ọmọ Húṣáì ní Ásérì àti ní Álótì;

17. Jèhósáfátì ọmọ Párúhà ni ó wà ní Ísákárì;

18. Síméì ọmọ Élà ni Bẹ́ńjámínì;

19. Gébérì ọmọ Úrì ní Gílíádì; orílẹ̀ èdè Ṣíhónì ọba àwọn ará Ámórì àti orílẹ̀ èdè Ógù ọba Básánì. Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 4