Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹni-Gébérì ní Rámótì-Gílíádì; tirẹ̀ ni àwọn ìletò Jáírì ọmọ Mànásè tí ń bẹ ní Gílíádì, tirẹ̀ sì ni agbégbé Ágóbù, tí ń bẹ ní Básánì, ọgọ́ta (60) ìlú tí ó tóbi pẹ̀lú odi tí ẹnu ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ irin.

Ka pipe ipin 1 Ọba 4

Wo 1 Ọba 4:13 ni o tọ