Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì sì fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn sí Olúwa nípa rírìn gẹ́gẹ́ bí òfin Dáfídì baba rẹ̀, àti pé, ó rú ẹbọ, ó sì fi tùràrí jóná ní ibi gíga.

Ka pipe ipin 1 Ọba 3

Wo 1 Ọba 3:3 ni o tọ