Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 3:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin tí ọmọ tirẹ̀ wà láàyè sì kún fún àánú fún ọmọ rẹ̀, ó sì wí fún ọba pé, “Jọ̀wọ́, Olúwa mi, ẹ fún un ní alààyè ọmọ! Ẹ má ṣe pa á!”Ṣùgbọ́n obìnrin èkejì sì wí pé, “Kì yóò jẹ́ tèmi tàbí tìrẹ̀. Ẹ gé e sí méjì!”

Ka pipe ipin 1 Ọba 3

Wo 1 Ọba 3:26 ni o tọ