Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì jí: ó sì mọ̀ pé àlá ni.Ó sì padà sí Jérúsálẹ́mù, ó sì dúró níwájú àpótí májẹ̀mú Olúwa, ó sì rúbọ ọrẹ sísun àti ẹbọ àlàáfíà. Nígbà náà ni ó ṣe àṣè fún gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 3

Wo 1 Ọba 3:15 ni o tọ