Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

èmi yóò ṣe ohun tí ìwọ ti béèrè. Èmi yóò fún ọ ní ọgbọ́n àti ọkàn ìmòye, tó bẹ́ẹ̀ tí kò fi ní sí ẹnìkan tí ó dà bí rẹ ṣáájú rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kì yóò dìde tí yóò dà bí rẹ lẹ́yìn rẹ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 3

Wo 1 Ọba 3:12 ni o tọ