Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì sì bá Fáráò ọba Éjíbítì dá àna, ó sì fẹ́ ọmọbìnrin rẹ̀ ní ìyàwó. Ó sì mú-un wá sí ìlú Dáfídì títí tí ó fi parí kíkọ́ ààfin rẹ̀ àti tẹ́ḿpìlì Olúwa, àti odi tí ó yí Jérúsálẹ́mù ká.

Ka pipe ipin 1 Ọba 3

Wo 1 Ọba 3:1 ni o tọ