Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésébélì aya rẹ̀ sì wí pé, “Ṣé báyìí ni ìwọ yóò ṣe ṣe bí ọba lórí Ísírẹ́lì? Dìde, jẹun! Kí o sì jẹ́ kí inú rẹ̀ dùn. Èmi yóò sì fún ọ ní ọgbà àjàrà Nábótì ará Jésérẹ́lì.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:7 ni o tọ